Best Awọn podcasts we could find (Updated April 2019)
Related podcasts: Islamic Religion Education Mọ Rọ Musulumi Ohun Ninu Isẹ Ẹkọ Rẹ Iroyin Wọn Irun Pupọ Nsẹlẹ Aisedeede Olugbe Alujannah Igbẹ)  
Awọn public [search 0]
×
Join millions of Player FM users today to get Awọn news and insights whenever you like, even when you're offline. Podcast smarter with the podcast app that refuses to compromise … it's free and easy.
Podcast smarter! Player FM is free and easy.
show episodes
 
Di? ninu aw?n okunfa ipanle, janduku ati aigb?ran ti aw?n ?m? ya kal? si awuj?.It?siwaju ninu alaye aw?n okunfa ipanle p?lu aw?n ?na abay? si aw?n iwa buburu yii.
 
Idanil?k? yii da lori aw?n Is? ti ?san w?n maa nbe gbere l?yin iku p?lu apejuwe lati inu ?gbawa hadisi.
 
Idanil?k? nipa aw?n ohun eew? ti o ti di gbajum? ni awuj? wa ni ode oni p?lu ?ri ikil? aw?n iwa ibaj? yii lati inu Alukuraani ati Sunnah Anabi.
 
Alaye lori aw?n ek? ati aw?n ohun ti o je dandan fun musulumi lati se nigbati o ba f? se igbans?, ?r? si tun waye lori aw?n aaye ti a k? fun ni lati se igbans? si.
 
Alaye nipa awon aaye ti ko leto ki Musulumi ki irun nibe gege bii ite oku ati ile egbin.
 
Idanil?k? yii da lori aw?n ?na ti musulumi fi le wa is? ?l?hun ati aabo R? g?g? bii: Jij? eso dabidun ‘ajiwa, sise aluwala loore koore, mima ki irun Fajri ni jama’a, mima ki irun oru, ati b?? b?? l?.
 
1- Ninu abala yi ?r? waye lori aw?n nkan ti o ye ki arinrinajo se ki o to b?r? irinajo r?. 2- Ninu abala yi ?r? waye l?kunr?r? lori aw?n ?k? ti o y? ki arinrinajo maa mu lo ni asiko ti ba nse irinajo r?.
 
Pataki irun kiki ati wipe ohun ni ak?k? ohun ti Musulumi yoo se isiro r? ni ?j? ajinde.Di? ninu aw?n aisedeede naa g?g? bii: aifarabal?, wiwo ?tun wosi lori irun ati b??b?? l?.
 
1- Idanil?k? yii s? nipa oniranran apejuwe nipa ibugbe Alujannah g?g? bi aw?n apejuwe yii se wa lati inu Alukuraani ati Sunnah Ojis? ?l?hun.2- Alaye lori aw?n is? ti o maa nse okunfa wiw? Alujannah g?g? bi ?l?hun ti se se iroyin r? lati inu Alukuraani ati Sunna.
 
Idanil?k? yii j? ki a m? aw?n orisi ?na ti aw?n Musulumi fi maa nkose aw?n ?l?sin miran p?lu aw?n eri lati inu Alukuraani ati aw?n ?gbawa hadisi ti o nk? fun Musulumi lori mima k?se aw?n ?l?sin miran.
 
1- Idanil?k? ni agbegbe yii s? aw?n ay?ka Alukuraani ati ?gbawa hadisi ti nse apejuwe bi Ina se ri.2- Alaye aw?n okunfa ti o maa nmu eniyan w? Ina, aw?n okunfa yii pin si meji: (1) Okunfa ti o maa nmu eniyan b? ninu Ina l? gbere, (2) okunfa ti o maa nmu Musulumi b? ninu Ina fun igba di?.
 
Ibanis?r? yii s? daradara ti o y? ki o maa ti ?w? musulumi kan jade si ?d? musulumi keji ati aw?n aburu ti o y? ki w?n maa le jina si ara w?n.
 
Alaye ni ?kunr?r? waye ninu idanil?k? yii lori ?k? ti o r? m? gbogbo ?ni ti n se is? sin eniyan.
 
1- Alaye lori Irun Ọdun mejeeji ati awọn ofin ti o rọ mọ aaye ikirun pẹlu awọn imura ti wọn fẹ ki a mu fun Irun ọdun.3- Idanileko ni apa yi da lori awọn ẹwa khutuba Ojise Olohun- ike ati ola Olohun ki o maa ba a- ni ọjọ odun ati tita koko ọrọ lori wipe se o maa ngbe minbari lọ si aaye ikirun ni tabi wọn mọ pa si ibẹ.
 
1- Ninu idanil?k? yii ?r? waye nipa aw?n ojuse ti Islam f? fun ?ni ti ko ni alaafia lati se ati aw?n ojuse ti ?sin f? fun aw?n olut?ju r? ki w?n se fun un.2- It?siwaju ninu alaye aw?n ojuse ti Islam f? fun aw?n olut?ju alaare lati se nigbati o ba np?kaka iku.3- Ni abala yii, alaye ti o kun waye nipa aw?n ojuse ti Islam f? ki a se nigba ti oku ba ku tan.
 
1- Ninu abala yi ?r? waye lori wipe ounj? ti ?l?hun Allah pese fun wa id?ra ni o j? ati alaye idi ti o fi j? id?ra. Bakannaa aw?n nkan ti o dara pup? lati se akiyesi r? nigba ti a ba f? j? ounj?. 2- Abala yii j? it?siwaju alaye lori aw?n ?k? ti o r? m? jij? ati mimu, ?kunr?r? alaye si waye lori aw?n nkan ti o dara pup? lati jina si ni asiko ti a ba f? j? tabi mu.
 
Loading …
show series
 
Google login Twitter login Classic login