Best idajo podcasts we could find (Updated February 2018)
Related podcasts: Nipa Ninu Tira Alaye Irun Lori Hadiisi Idajọ Islamic Religion Education Esin Awon Islam Ahkaam Umdatul Buluugul-maraam Lilo Itanran Jimoh  
Idajo public [search 0]
show episodes
 
I
Idajo Esin Lori Pipa Eniyan
Daily+
 
Waasi yi se alaye ni ekunrere oro nipa idajo eni ti o ba pa eniyan ninu esin Islam, yala o moomo pa eniyan ni tabi o seesi.
 
A
Awọn Idajọ ti o rọ mọ Oku
 
1- Ninu idanilẹkọ yii ọrọ waye nipa awọn ojuse ti Islam fẹ fun ẹni ti ko ni alaafia lati se ati awọn ojuse ti Ẹsin fẹ fun awọn olutọju rẹ ki wọn se fun un.2- Itẹsiwaju ninu alaye awọn ojuse ti Islam fẹ fun awọn olutọju alaare lati se nigbati o ba npọkaka iku.3- Ni abala yii, alaye ti o kun waye nipa awọn ojuse ti Islam fẹ ki a se nigba ti oku ba ku tan.
 
I
Idajọ biba Keferi kopa ninu Ọdun wọn
 
Idanilẹkọ yi sọ nipa itumọ biba awọn keferi kopa ninu ọdun wọn pẹlu awọn ẹri lorisirisi lori bi biba awọn keferi kopa ninu ọdun wọn se jẹ eewọ fun Musulumi.
 
I
Idajo ati Aworan Kikọse Awọn Keferi
 
Idanilẹkọ yii jẹ ki a mọ awọn orisi ọna ti awọn Musulumi fi maa nkose awọn ẹlẹsin miran pẹlu awọn eri lati inu Alukuraani ati awọn ẹgbawa hadisi ti o nkọ fun Musulumi lori mima kọse awọn ẹlẹsin miran.
 
I
Idajo Islam lori Orin kiko ati Gbigbo
 
Waasi yi so nipa idajo Islam lori orin kiko ati gbigbo. Oniwaasi mu awon eri ti o po wa lati inu Al-kurani ati hadiisi lori bi orin gbigbo ati kiko se je eewo ninu Islam. Bakannaa ni oro waye ninu waasi yi lori awon aburu repete ti o wa nibi gbigbo orin ati kiko.
 
I
Idajo Islam lori Owo Ele (Riba)
 
Idanilẹkọ yii se afihan iha ti Islam kọ si owo ele ni gbagba pẹlu idajọ rẹ ati orisi ọna ti owo ele ni gbigba pin si.
 
I
Idajọ Ẹsin lori Rukiya, Oogun Ifẹ ati Gbekude lilo
 
Idanilẹkọ yii da lori awọn koko wọnyii:(i) Iha ti ẹsin ko si Rukiya, Oogun ifẹ ati Gbekude lilo,(ii) Idajọ awọn nkan mẹtẹẹta yii,(iii) Majẹmu Rukiya,(iv) Idajọ wiwe ayah Alukuraani ati dide mọ ọrun,(v) Diẹ ninu awọn Rukiya ti a le fi se isọ fun alaarẹ, ọmọde ati lati fi wa iwosan.
 
A
Awon Idajo Esin Nipa Aja Ati Egbin re
 
Idanileko yi je alaye nipa hadiisi eleekefa ninu tira “Umdatul Ahkaam”. Oludanileko so nipa egbin aja ati awon idajo ti o ro mo o, o si tun so nipa awon agbegbe ti esin ti gba awa Musulumi laaye lati se anfaani lara aja gege bii fifi so ile ati beebee lo
 
I
Idajo Islam lori Odun Ayajo Ojo Ololufe (Valentine Day)
 
1- Ibanisoro yii se alaye ibi ti Odun ayajo ojo ololufe (Valentine) ti wa, ati Idajo Islam lori re.2- Eleyi ni akotan lori oro nipa odun ayajo ojo ololufe (Valentine).
 
I
Idajọ Irun ti a fi n wa Ojo (Sọlaatul-istiskaai)
 
Eyi ni ẹkunrẹrẹ alaye lori bi Ojise Olohun- ike ati ola Olohun ki o maa ba a- se maa n ki Irun Itọrọ Ojo pẹlu sise afihan awọn orisirisi ọna ti o gba se adua lati tọrọ ojo nigba aye rẹ.
 
I
Idajo Esin Lori Gbigba Aawe ni Ojo Jimoh
 
Eyi ni alaye awon Hadisi ti o n so nipa awon ojo ti Shari’ah ko fun Musulumi lati maa gba aawe ninu won ati awon eko esin ti o ro mo won.
 
O
Ola ti o wa fun Irun Pipe ati Awon Idajo Esin ti o sopo mo o
 
Alaye nipa ola ti o nbe fun irun pipe ati awon idajo esin ti o ro m o o, olubanisoro se alaye wipe Ojise Olohun – ike ati ola Olohun ki o maa ba a- kii pe irun tabi se ikaama fun irun odun mejeeji: odun itunu aawe ati odun ileya.
 
I
Idajọ ki Musulumi jẹ Ẹran ti Yahudi ati Nasara ba pa
 
Idanilẹkọ ti o se alaye: (1) Idajọ ẹran ti Musulumi ba pa, yala o da orukọ Ọlọhun si ni tabi ko da orukọ Ọlọhun si ni latari igbagbe. (2) Idajọ Ẹran ti Yahudi tabi Nasara ba pa yala fun ọdun ni tabi fun nkan miran. (3) Idajọ gbogbo ẹran ti wọn ba pa laida orukọ Ọlọhun sii.
 
A
Alaye Hadiisi Nipa Idajo Nkan Osu Obinrin Ninu Tira Umdatul Ahkaam
 
Eyi ni alaye awon Haadisi tinso nipa Eje Nkan Osu Obinrin lati inu tira ‘Umudatul Haakaam’, ti olubanisoro si s’alaye awon idajo esin ti o ro mo.
 
I
Idajọ Irun ti a maa nki nigbati Ọsan ba di Oru (Sọlaatul-Kusuuf)
 
Alaye waye ninu waasi yi nipa bi Ojise Olohun- ike ati ola Olohun ki o maa ba a- ti se ki irun bi osan ba di oru ni oju aye re pelu awon idajo irun yii. Oro si tun waye lori wipe oorun ati osupa ninu awon amin agbara Olohun ni won wa, won kii wo okunkun nitori iku eniyan kan tabi wiwa laaye re.
 
A
Alaye Awon Hadiisi nipa Imora Oniyagbe (Tayammum) ninu Tira Buluugul-maroom
 
Alaye nipa imora oniyagbe (imora ti kosi omi nibe) ati awon idajo esin ti o so mo o.
 
A
Aluwala Oniyagbẹ (At-Tayammum)
 
Idanilẹkọ yii da lori idajọ aluwala oniyagbẹ (at-tayammum), ati wipe nigba wo ni a le se e ati bi a se nse e.
 
E
Esin Islam ati Oro nipa Eto Oselu Tiwa- ntiwa (Demokiresi)
 
1- Eleyi ni oro nipa ohun ti o je ojuse Musulumi nibi ibo didi ati idajo Islam lori kikopa ninu idibo.2- Itesiwaju nipa ohun ti Islam so lori eto oselu tiwa- ntiwa (Demokiresi), olubanisoro menu ba idajo esin lori dida egbe oselu sile ati kikopa ninu re, o si tun so nipa ojuse eniti o ba fe gbegba fun ipo oselu.
 
A
Alaye Awon Hadiisi nipa Gbigba Iwaju Eni ti o ba n ki Irun koja ninu Tira “Umdatul Ahkaam”
 
Idanileko yi so alaye gbogbo awon idajo ti o ro mo gbigba iwaju eni ti o ba n ki irun koja, yala eni ti o fi nkan si iwaju re tabi eni ti ko fi nkankan si iwaju.
 
A
Alaye Itumo Awon Hadiisi ti o so nipa Irun Pipe ninu tira Umdatul Ahkaam
 
Idanileko yi so nipa awon idajo esin ti o ro mo irun pipe, oniwaasi so oro nipa re ni ifosiwewe nigbati o nse alaye awon hadiisi ti o ro mo o.
 
A
Alaye Hadiisi ti o so nipa Itanran eniti o ni Ajosepo Pelu Eleto Re ni Osan Ramadan
 
Koko idanileko yi ni oro nipa itanran ti o nbe fun eni ti o ni ajosepo pelu eleto re ni osan Ramadan, oniwaasi se alaye re ni ekunrere o si tun menu ba awon idajo miran.
 
A
Alaye Hadiisi ti o so nipa Sakaatu Fitri ninu tira Umdatul Ahkaam
 
Eleyi ni itumo awon hadiisi kan ti o so nipa sakaatul fitri ti awon Yoruba npe ni jaka. Oniwaasi se alaye awon idajo esin ti o ro mo o gege bii awon ti o ye ki o yo o, irufe ounje ti a fi maa nyo o ati odiwon ti o ye ki a yo.
 
I
Iforikanlẹ Itanran Igbagbe lori Irun
 
Awọn koko Idanilẹkọ yi: (i) Awọn ohun mẹta ti o maa nse okunfa iforikanlẹ itanran igbagbe lori Irun. (ii) Awọn aaye ti a ti maa nse iforikanlẹ itanran igbagbe, siwaju salamọ ni tabi lẹyin salamọ. (iii) Awọn idajọ ti o rọ mọ iforikanlẹ itanran igbagbe.
 
I
Igbaniyanju Lori Lilo si Aaye Ikirun ni Asiko Odun Aawe ati Ileya
 
Ibanisoro yi da lori Pataki odun mejeeji ninu Islam: odun itunu aawe ati odun ileya, olubanisoro si so bi ojise Olohun se gba awa Musulumi ni iyanju lori kiko awon ara ile wa lo si aaye ikirun ni ojo odun. Ni afikun, o tun so die nipa idajo Janaba ati eje nkan osu obinrin.
 
A
Alaye nipa Irun Onirin-ajo ati Alaare ninu tira Buluugul-maraam
 
1- Idanileko yi soro nipa bi arinrin-ajo ati alaare yoo se maa ki irun won laini fi wole tabi lo o lara tayo asiko re.2- Kiki irun rakah merin ni meji ni ori irinajo ati ki alaare fi aawe sile ninu osu Ramadan ki o si gba a pada nigbati ara re ba ya gbogbo eleyi je irorun ti Olohun se fun awa Musulumi ti O si fe ki a maa je anfaani re nitoripe irorun ni Olohun fe fun wa ninu Esin Islam.3- Alaye ni ekunrere lori awon idajo irun onirin-ajo, igba ti yoo maa bere si din irun re ku ati asiko ti y ...
 
A
Alaye nipa Irun Jimoh ninu tira Buluugul-maraam
 
2- Alaye lori awon idajo ti o sopo mo irun Jimoh, ninu won ni: (1) Asiko wo ni irun Jimoh maa n wole. (2) Onka wo ni o ye ki o pe ki a to le ki irun Jimoh. (3) Rakah melo ni Musulumi gbodo ba ki o to le gba pe oun ba irun Jimoh.3- Alaye lori wipe Ojise Olohun- ike ati ola Olohun ki o maa ba a maa n gbe ohun soke ni ti o ba n se khutuba ti o si maa n se khutuba ni iduro, gbogbo awon nkan wonyi ni o si maa n se okunfa ki khutuba ni ilapa lara awon ti won n gbo o.4- Oro waye ni apa kerin yi lor ...
 
Loading …
show series
 
T
Today in iOS Podcast - The Unofficial iOS, iPhone, iPad, and Apple Watch News and iPhone Apps Podcast
 
Tii - iTem 0393 - iOS 9.3.3 Beta 1 Give us a call - 1-206-666-6364 Send us an email - todayinios@gmail.com Links Mentioned in Today's Episode: Today's Sponsor - MTailor App - Promo Code = tii iOS 9.3.2 Problems: Error 56 Apple Seeds First Beta of iOS 9.3.3 to Developers Apple Tweaks Touch ID Rules With a Notable Addition Apple’s Touch ID rules ...…
 
T
Today in iOS Podcast - The Unofficial iOS, iPhone, iPad, and Apple Watch News and iPhone Apps Podcast
 
Tii - iTem 0393 - iOS 9.3.3 Beta 1 Give us a call - 1-206-666-6364 Send us an email - todayinios@gmail.com Links Mentioned in Today's Episode: Today's Sponsor - MTailor App - Promo Code = tii iOS 9.3.2 Problems: Error 56 Apple Seeds First Beta of iOS 9.3.3 to Developers Apple Tweaks Touch ID Rules With a Notable Addition Apple’s Touch ID rules ...…
 
I
Idajọ Ẹsin lori Rukiya, Oogun Ifẹ ati Gbekude lilo
 
Idajọ Ẹsin lori Rukiya, Oogun Ifẹ ati Gbekude lilo
 
A
Awọn Idajọ ti o rọ mọ Oku
 
Awọn Idajọ ti o rọ mọ Oku - 1
 
A
Awọn Idajọ ti o rọ mọ Oku
 
Awọn Idajọ ti o rọ mọ Oku - 2
 
A
Awọn Idajọ ti o rọ mọ Oku
 
Awọn Idajọ ti o rọ mọ Oku - 3
 
I
Idajo Islam lori Owo Ele (Riba)
 
Idajo Islam lori Owo Ele (Riba)
 
I
Idajọ biba Keferi kopa ninu Ọdun wọn
 
Idajọ biba Keferi kopa ninu Ọdun wọn
 
I
Idajọ ki Musulumi jẹ Ẹran ti Yahudi ati Nasara ba pa
 
Idajọ ki Musulumi jẹ Ẹran ti Yahudi ati Nasara ba pa
 
I
Idajo ati Aworan Kikọse Awọn Keferi
 
Idajo ati Aworan Kikọse Awọn Keferi
 
Featuring author/host Michael Perry, Blue Canvas Orchestra and special musical guests Ida Jo and Blessed Feathers. Live from the Capitol Theater in beautiful downtown Madison, Wisconsin.
 
I
Idajọ Irun ti a fi n wa Ojo (Sọlaatul-istiskaai)
 
Idajọ Irun ti a fi n wa Ojo (Sọlaatul-istiskaai)
 
I
Idajọ Irun ti a maa nki nigbati Ọsan ba di Oru (Sọlaatul-Kusuuf)
 
Idajọ Irun ti a maa nki nigbati Ọsan ba di Oru (Sọlaatul-Kusuuf)
 
O
Ola ti o wa fun Irun Pipe ati Awon Idajo Esin ti o sopo mo o
 
Ola ti o wa fun Irun Pipe ati Awon Idajo Esin ti o sopo mo o
 
I
Idajo Esin Lori Pipa Eniyan
 
Idajo Esin Lori Pipa Eniyan
 
I
Idajo Islam lori Odun Ayajo Ojo Ololufe (Valentine Day)
 
Idajo Islam lori Odun Ayajo Ojo Ololufe (Valentine Day) - 1
 
I
Idajo Islam lori Odun Ayajo Ojo Ololufe (Valentine Day)
 
Idajo Islam lori Odun Ayajo Ojo Ololufe (Valentine Day) - 2
 
I
Idajo Esin Lori Gbigba Aawe ni Ojo Jimoh
 
Idajo Esin Lori Gbigba Aawe ni Ojo Jimoh
 
A
Alaye Hadiisi Nipa Idajo Nkan Osu Obinrin Ninu Tira Umdatul Ahkaam
 
Alaye Hadiisi Nipa Idajo Nkan Osu Obinrin Ninu Tira Umdatul Ahkaam
 
A
Awon Idajo Esin Nipa Aja Ati Egbin re
 
Awon Idajo Esin Nipa Aja Ati Egbin re
 
I
Idajo Islam lori Orin kiko ati Gbigbo
 
Idajo Islam lori Orin kiko ati Gbigbo
 
M
MAD TOAST LIVE!
 
Ida Jo, a fixture in the Madison music scene, returns to the show with Scott Lamps. Her soulful voice and unique songwriting a must listen. www.idajo.com Video http://youtu.be/ddK6bsH4kTI
 
Recently voted of Madison’s Songwriter of the Year, Corey Hart plays the music you wish you'd grown up to - an eclectic blend of folk, rock, and a little bit of soul. Corey is joined by Ida Jo on the fiddle. We are happy to have them back on the show! coreyhartmusic.com
 
IDA JO Courage. Strength. Devotion. Ida Jo's debut album "Providence" is about all those things and is available now on iTunes, CDBaby, and Amazon. Nominated for several Madison Area Music Awards, including String Instrumentalis of the Year, as well as Pop Album, Pop Song, and R&B Song for her work with Mike Droho & The Compass Rose, Ida Jo wil ...…
 
Speed
Series preference
1x
1x
Volume
100%
/

Google login Twitter login Classic login