Best odun podcasts we could find (Updated February 2018)
Related podcasts: Ninu Alaye Irun Islamic Religion Education Lori Idajọ Idajo Nipa Ohun] [agbekale Alaponle Alukurani Igbeyin Idamewa Sopo Buluugul-maraam Buluugul-maraam Tira  
Odun public [search 0]
show episodes
 
I
Idajọ biba Keferi kopa ninu Ọdun wọn
 
Idanilẹkọ yi sọ nipa itumọ biba awọn keferi kopa ninu ọdun wọn pẹlu awọn ẹri lorisirisi lori bi biba awọn keferi kopa ninu ọdun wọn se jẹ eewọ fun Musulumi.
 
A
Alaye nipa Irun Odun Mejeeji ninu tira Buluugul-maraam
 
1- Alaye lori Irun Ọdun mejeeji ati awọn ofin ti o rọ mọ aaye ikirun pẹlu awọn imura ti wọn fẹ ki a mu fun Irun ọdun.3- Idanileko ni apa yi da lori awọn ẹwa khutuba Ojise Olohun- ike ati ola Olohun ki o maa ba a- ni ọjọ odun ati tita koko ọrọ lori wipe se o maa ngbe minbari lọ si aaye ikirun ni tabi wọn mọ pa si ibẹ.
 
I
Idajo Islam lori Odun Ayajo Ojo Ololufe (Valentine Day)
 
1- Ibanisoro yii se alaye ibi ti Odun ayajo ojo ololufe (Valentine) ti wa, ati Idajo Islam lori re.2- Eleyi ni akotan lori oro nipa odun ayajo ojo ololufe (Valentine).
 
I
Igbaniyanju Lori Lilo si Aaye Ikirun ni Asiko Odun Aawe ati Ileya
 
Ibanisoro yi da lori Pataki odun mejeeji ninu Islam: odun itunu aawe ati odun ileya, olubanisoro si so bi ojise Olohun se gba awa Musulumi ni iyanju lori kiko awon ara ile wa lo si aaye ikirun ni ojo odun. Ni afikun, o tun so die nipa idajo Janaba ati eje nkan osu obinrin.
 
A
Alaye itumo idamewa igbeyin ninu alukurani alaponle ni ede yoruba [agbekale ti ohun]
 
Awon apo-iwe ti ohun fun kika idamewa igbeyin ninu alukurani alaponle, awon naa ni: eleekeji-din-logbon, eleekokan-din-logbon ati ogbon, pelu itumo re ni ede yoruba pelu ohun ti o dun, ti o wu eti gbo.
 
O
Ola ti o wa fun Irun Pipe ati Awon Idajo Esin ti o sopo mo o
 
Alaye nipa ola ti o nbe fun irun pipe ati awon idajo esin ti o ro m o o, olubanisoro se alaye wipe Ojise Olohun – ike ati ola Olohun ki o maa ba a- kii pe irun tabi se ikaama fun irun odun mejeeji: odun itunu aawe ati odun ileya.
 
I
Idajọ ki Musulumi jẹ Ẹran ti Yahudi ati Nasara ba pa
 
Idanilẹkọ ti o se alaye: (1) Idajọ ẹran ti Musulumi ba pa, yala o da orukọ Ọlọhun si ni tabi ko da orukọ Ọlọhun si ni latari igbagbe. (2) Idajọ Ẹran ti Yahudi tabi Nasara ba pa yala fun ọdun ni tabi fun nkan miran. (3) Idajọ gbogbo ẹran ti wọn ba pa laida orukọ Ọlọhun sii.
 
A
Alaye nipa Irun Jimoh ninu tira Buluugul-maraam
 
2- Alaye lori awon idajo ti o sopo mo irun Jimoh, ninu won ni: (1) Asiko wo ni irun Jimoh maa n wole. (2) Onka wo ni o ye ki o pe ki a to le ki irun Jimoh. (3) Rakah melo ni Musulumi gbodo ba ki o to le gba pe oun ba irun Jimoh.3- Alaye lori wipe Ojise Olohun- ike ati ola Olohun ki o maa ba a maa n gbe ohun soke ni ti o ba n se khutuba ti o si maa n se khutuba ni iduro, gbogbo awon nkan wonyi ni o si maa n se okunfa ki khutuba ni ilapa lara awon ti won n gbo o.4- Oro waye ni apa kerin yi lor ...
 
Loading …
show series
 
R
Road To Stardom Radio
 
WUZ GOODY GOOD YOU ARE TUNED INTO THE INDIE EXPERIENCE ON ROAD TO STARDOM RADIO WITH YOUR HOST MSGIGO TONITE YOU ARE GOING TO HEAR THE BEST IN INDIE MUSIC WITH SOME THROWBACKS THROWN IN FROM ARTIST LIKE ADMIRAL, CALVIN RICHARDSON, TOO RAPS, XAVIER LEWIS, CLEVA THOUGHTS, MICHELLE SINGZ,TREY MILLER, ELLIOT MAURICE AND DIESEL SO SIT BACK RELAX AND ...…
 
Hosted by Tommaso Cappellatorocketradiolive.com*Soundcloud only stream at 128kbs, for high quality stream check our directory:rocketradiolive.com/broadcastTRACKLIST:John & Alice Coltrane - Reverend King / Giovanni Paolo XXIII - Dal Discorso di Apertura del Consiglio Ecumenico Vaticano II - 1962Les Lisu (Musique Des Tribus Chinois Du Triangle D' ...…
 
Q
QueenMother4real Media
 
Eku Odun (Happy New Year) 2016 and all that we shall walk and endure together in the upliftment of our collective destiny.We have all entered this nine vibration for better or worse...? Sista Queens rising...and shining...is a called to the sacred activism of Who we are , what we do and how we doi it... the marriage of spiritualist with natural ...…
 
I
Idajọ biba Keferi kopa ninu Ọdun wọn
 
Idajọ biba Keferi kopa ninu Ọdun wọn
 
A
Alaye nipa Irun Odun Mejeeji ninu tira Buluugul-maraam
 
Alaye nipa Irun Odun Mejeeji ninu tira Buluugul-maraam -1
 
A
Alaye nipa Irun Odun Mejeeji ninu tira Buluugul-maraam
 
Alaye nipa Irun Odun Mejeeji ninu tira Buluugul-maraam -3
 
I
Idajo Islam lori Odun Ayajo Ojo Ololufe (Valentine Day)
 
Idajo Islam lori Odun Ayajo Ojo Ololufe (Valentine Day) - 1
 
I
Idajo Islam lori Odun Ayajo Ojo Ololufe (Valentine Day)
 
Idajo Islam lori Odun Ayajo Ojo Ololufe (Valentine Day) - 2
 
I
Igbaniyanju Lori Lilo si Aaye Ikirun ni Asiko Odun Aawe ati Ileya
 
Igbaniyanju Lori Lilo si Aaye Ikirun ni Asiko Odun Aawe ati Ileya
 
Speed
Series preference
1x
1x
Volume
100%
/

Google login Twitter login Classic login