Best owuo podcasts we could find (Updated February 2018)
Related podcasts: Religion Islamic Education Awọn Ninu Lori Musulumi Islam Ohun] [agbekale Alaponle Alukurani Igbeyin Idamewa (Ọla Anọbi Itan Diẹ Nakatua Adia  
Owuo public [search 0]
show episodes
 
O
Owuo ahometew
Daily+
 
Kasamu: • Owuo ahometew.
 
S
Siraha/Papaye ema owuo foɔ eni Mpae emanu
 
Kasamu : Siraha/Papaye ema owuo foɔ eni Mpae emanu.
 
A
Adia a Nakatua be tu gye di ne ewu ne owuo ekyiri
 
Kasamu : Adia a Nakatua be tu gye di ne ewu ne owuo ekyiri.
 
I
Idajo Islam lori Owo Ele (Riba)
 
Idanilẹkọ yii se afihan iha ti Islam kọ si owo ele ni gbagba pẹlu idajọ rẹ ati orisi ọna ti owo ele ni gbigba pin si.
 
A
Awọn Ohun Eewọ ti apakan ninu awọn Musulumi fi ọwọ yẹpẹrẹ mu
 
Idanilẹkọ nipa awọn ohun eewọ ti o ti di gbajumọ ni awujọ wa ni ode oni pẹlu ẹri ikilọ awọn iwa ibajẹ yii lati inu Alukuraani ati Sunnah Anabi.
 
P
Prophecy at the Midnight Hour
Monthly+
 
This is what the Sovereign Lord says: From the four winds come in, O Spirit, and breathe on these slain, that they may live. Ezekiel: 37:9 The long awaited Joel End Time Revival (Joel 2:28) is now global.http://www.repentandpreparetheway.org
 
A
Alaye itumo idamewa igbeyin ninu alukurani alaponle ni ede yoruba [agbekale ti ohun]
 
Awon apo-iwe ti ohun fun kika idamewa igbeyin ninu alukurani alaponle, awon naa ni: eleekeji-din-logbon, eleekokan-din-logbon ati ogbon, pelu itumo re ni ede yoruba pelu ohun ti o dun, ti o wu eti gbo.
 
A
Awon Okunfa Isubu Oro-aje Orile-ede
 
Iyapa Olohun Allah ati owo ele ni okunfa meji ti o lagbara julo fun isubu oro-aje, imoran si tun waye lori awon ona abayo si isoro yii.
 
A
Awọn Ojuse Musulumi si ara wọn
 
Ibanisọrọ yii sọ daradara ti o yẹ ki o maa ti ọwọ musulumi kan jade si ọdọ musulumi keji ati awọn aburu ti o yẹ ki wọn maa le jina si ara wọn.
 
I
Iwọ Aladugbo
Daily+
 
1- Idanilẹkọ yi sọ nipa itumọ aladugbo pẹlu itọka rẹ lati inu Alukurani, bakannaa ọrọ tun waye lori diẹ ninu awọn iwọ aladugbo gẹgẹ bii ki Musulumi jẹ ki ọkan aladugbo rẹ balẹ, ki o ma je ki suta tabi aburu wa lati ọwọ rẹ si aladugbo rẹ.2- Itẹsiwaju alaye lori awọn iwọ aladugbo, ọrọ waye nibẹ wipe ninu awọn iwọ aladugbo yoku ni: didaabobo o, sise daradara si i, sise amumọra fun aburu ọwọ rẹ ati bẹẹbẹẹ lọ.
 
A
Asigbọ lori Akoko Irun Jimọh
 
Idanilẹkọ yii se alaye ọrọ awọn onimimọ ti o da lori igba ti o yẹ ki a maa ki Irun Jimọh, ni idahun si asigbọye ẹsin eyi ti o n waye lati ọwọ ikọ awọn ọdọ Musulumi kan ti wọn ngbe Irun Jimọh duro ni aago mẹsan awurọ.
 
E
Egbe Alajeseku Ninu Islam (Islamic Co-Operative)
 
1- Alaye ni ekunrere lori eto ise egbe alajeseku ni ilana ti Islam, ati alaye nipa aburu ti o nbe nibi owo-ele (Riba), eri re lati inu Alukuraani mimo ati Oro Ojise Olohun.2-Alaye ni afikun lori awon okowo ti Islam gbe kale ti a le maa lo ninu egbe alajeseku gege bii: Musharakah, Mudarabah, Murabahah ati bee bee lo.
 
D
Diẹ nipa Itan Anọbi Isa (Ọla Ọlọhun ki o maa ba a)
 
1- Alaye waye ni agbegbe yii lori itan ranpẹ nipa ẹni tii se iya-iya Anọbi Isa ati iya rẹ pẹlu alaye nipa bi bibi rẹ se waye.2- Ọrọ waye ni abala yii nipa awọn isẹ iyanu ti Ọlọhun se lati ọwọ Anọbi Isa. Ibeere si waye wipe se ọmọ Ọlọhun ni Anọbi Isa bi?3- Idanilẹkọ ni agbegbe yii pese idahun si awọn ibeere wọnyii:- Njẹ Anọbi Isa ku ati wipe nibo ni o ku si?- Njẹ Anọbi Isa npada bọ wa si aye, ati wipe igba wo ni?- Ki ni yoo sẹlẹ ni asiko pipadabọọ rẹ?- Awọn ẹri ti o da lori pipadabọọ rẹ.
 
M
Men In Sheds
Monthly
 
Cars, loads of people talk about them, don’t they? Well, we do too. We prattle on about ’em like a couple of two stroke diesels as we guzzle an endless supply of tea like it’s an endless supply of oil. Ooh! Controversial that. That’s just the kind of contentious guff we’re not afraid to address, as we sit back in a shed, and comment on the world going on around us. And it’s not like we’re pro-electric, anti-diesel, or anything like that. We’re a right pair of tarts we are. We like all kinds ...
 
Loading …
show series
 
O
Owuo ahometew
 
Owuo ahometew 3
 
O
Owuo ahometew
 
Owuo ahometew 4
 
O
Owuo ahometew
 
Owuo ahometew 2
 
A
Adia a Nakatua be tu gye di ne ewu ne owuo ekyiri
 
Adia a Nakatua be tu gye di ne ewu ne owuo ekyiri
 
S
Siraha/Papaye ema owuo foɔ eni Mpae emanu
 
Siraha/Papaye ema owuo foɔ eni Mpae emanu
 
Speed
Series preference
1x
1x
Volume
100%
/

Google login Twitter login Classic login