Best ninu podcasts we could find (Updated May 2018)
Related podcasts: Alaye Nipa Awon Tira Awọn Islam Hadiisi Irun Islamic Religion Education Lori Esin Ahkaam Umdatul Idajo Ohun Mọ Rọ Saka  
Ninu public [search 0]
show episodes
 
1- Ninu abala yi ọrọ waye lori awọn nkan ti o ye ki arinrinajo se ki o to bẹrẹ irinajo rẹ. 2- Ninu abala yi ọrọ waye lẹkunrẹrẹ lori awọn ẹkọ ti o yẹ ki arinrinajo maa mu lo ni asiko ti ba nse irinajo rẹ.
 
1- Oro waye ninu waasi yi lori Itumo gbolohun Islam ati alaye bi o se je wipe ijosin Ojise Olohun, iwa re ati ise re je apejuwe ti o daju fun itumo paapaa esin Islam. Oro si tun waye lori bi ’waayi’ se maa n so kale fun Ojise Olohun.2- Ninu awon Ewa esin Islam ti oniwaasi menu ba ninu apa keji yi ni bi Islam se je esin gbogbo abgaye, ti o tun je esin ti o pe perepere, bakannaa ti o si je esin ti o rorun julo.
 
Awọn koko idanilẹkọ yii: (1) Alaye itumọ ibẹru Ọlọhun ninu irun kiki pẹlu apejuwe rẹ nibi isesi awọn ẹni-isaaju ti wọn jẹ ẹni-rere. (2) Itaniji si awọn isesi kan ti ko lẹtọ ninu irun. (3) Awọn ohun ti o le se okunfa ibẹru Ọlọhun ninu irun.
 
Awon apo-iwe ti ohun fun kika idamewa igbeyin ninu alukurani alaponle, awon naa ni: eleekeji-din-logbon, eleekokan-din-logbon ati ogbon, pelu itumo re ni ede yoruba pelu ohun ti o dun, ti o wu eti gbo.
 
1- Alaye ni ekunrere lori eto ise egbe alajeseku ni ilana ti Islam, ati alaye nipa aburu ti o nbe nibi owo-ele (Riba), eri re lati inu Alukuraani mimo ati Oro Ojise Olohun.2-Alaye ni afikun lori awon okowo ti Islam gbe kale ti a le maa lo ninu egbe alajeseku gege bii: Musharakah, Mudarabah, Murabahah ati bee bee lo.
 
Idanilẹkọ yii da lori awọn koko mẹta wọnyii: (i) Pataki asepọ jijẹ ọmọ iya ninu ẹsin. (ii) Ẹsan ti o wa fun asepọ ọmọ iya ninu ẹsin. (iii) Awọn nkan ti o maa nba jijẹ ọmọ iya ninu ẹsin jẹ.
 
Ibanisoro se alaye awon eto wonyi: (i) Eto oko lori aya, (ii) Eto Aya lori oko, (iii) Eto ti awon mejeeji ni si ara won.
 
1- Eleyi ni iforowero laarin Ijo Ahmadiyyah ati Ijo Tadomun Muslimeen lori wipe se Annabi Isa- ike ati ola Olohun ki o maa ba a- ku si ori igi agbelebu ni tabi ko ku, se won gbe gun Sanmo lo ni tabi o wa ni ibikan lori ile aye yii.2- Eleyi ni itesiwaju iforowero laarin igun mejeeji pelu awon eri olukuluku won lati le fi oro won mule.
 
Idanilẹkọ yi sọ nipa itumọ biba awọn keferi kopa ninu ọdun wọn pẹlu awọn ẹri lorisirisi lori bi biba awọn keferi kopa ninu ọdun wọn se jẹ eewọ fun Musulumi.
 
1- Alaye wa ninu idanilẹkọ yii lori: (1) Itumọ ikẹ ati aanu gẹgẹ bi awọn onimimọ ẹsin se se alaye rẹ. (2) Diẹ ninu awọn agbegbe ti ikẹ ati aanu ti gbodo maa waye gẹgẹ bii ki olori se ikẹ fun awọn ọmọlẹyin rẹ ati sise aanu fun awọn ọmọde.2- Alaye waye ni apa yii lori: (1) Awọn agbegbe yoku ti o ti yẹ ki eniyan ti maa se aanu. (2) Awọn anfaani ti o wa ninu aanu sise. (3) Sise daradara pẹlu awọn ẹranko naa wa lara aanu sise.
 
1- Alaye lori Irun Ọdun mejeeji ati awọn ofin ti o rọ mọ aaye ikirun pẹlu awọn imura ti wọn fẹ ki a mu fun Irun ọdun.3- Idanileko ni apa yi da lori awọn ẹwa khutuba Ojise Olohun- ike ati ola Olohun ki o maa ba a- ni ọjọ odun ati tita koko ọrọ lori wipe se o maa ngbe minbari lọ si aaye ikirun ni tabi wọn mọ pa si ibẹ.
 
2- Alaye lori awon idajo ti o sopo mo irun Jimoh, ninu won ni: (1) Asiko wo ni irun Jimoh maa n wole. (2) Onka wo ni o ye ki o pe ki a to le ki irun Jimoh. (3) Rakah melo ni Musulumi gbodo ba ki o to le gba pe oun ba irun Jimoh.3- Alaye lori wipe Ojise Olohun- ike ati ola Olohun ki o maa ba a maa n gbe ohun soke ni ti o ba n se khutuba ti o si maa n se khutuba ni iduro, gbogbo awon nkan wonyi ni o si maa n se okunfa ki khutuba ni ilapa lara awon ti won n gbo o.4- Oro waye ni apa kerin yi lor ...
 
Idanilẹkọ nipa awọn ohun eewọ ti o ti di gbajumọ ni awujọ wa ni ode oni pẹlu ẹri ikilọ awọn iwa ibajẹ yii lati inu Alukuraani ati Sunnah Anabi.
 
Eyi ni alaye awon Haadisi tinso nipa Eje Nkan Osu Obinrin lati inu tira ‘Umudatul Haakaam’, ti olubanisoro si s’alaye awon idajo esin ti o ro mo.
 
Ibanisoro yi so ni ekunrere nipa itumo adadaale ninu esin pelu awon eri lati inu Al-kurani ati Sunna Ojise. O si se alaye ewu ti o wa nibi ki musulumi maa tele awon ti won ba n da adadaale ninu esin. Ni afikun, o tun se alaye awon majemu ti a fi maa nmo adadaale nitori awon iruju ti o wa fun awon Musulumi kan lori re.
 
Eleyi ni itumo awon hadiisi kan ti o so nipa sakaatul fitri ti awon Yoruba npe ni jaka. Oniwaasi se alaye awon idajo esin ti o ro mo o gege bii awon ti o ye ki o yo o, irufe ounje ti a fi maa nyo o ati odiwon ti o ye ki a yo.
 
Idanileko yi so nipa awon idajo esin ti o ro mo irun pipe, oniwaasi so oro nipa re ni ifosiwewe nigbati o nse alaye awon hadiisi ti o ro mo o.
 
1- Idanileko yi soro nipa bi arinrin-ajo ati alaare yoo se maa ki irun won laini fi wole tabi lo o lara tayo asiko re.2- Kiki irun rakah merin ni meji ni ori irinajo ati ki alaare fi aawe sile ninu osu Ramadan ki o si gba a pada nigbati ara re ba ya gbogbo eleyi je irorun ti Olohun se fun awa Musulumi ti O si fe ki a maa je anfaani re nitoripe irorun ni Olohun fe fun wa ninu Esin Islam.3- Alaye ni ekunrere lori awon idajo irun onirin-ajo, igba ti yoo maa bere si din irun re ku ati asiko ti y ...
 
Alaye nipa imora oniyagbe (imora ti kosi omi nibe) ati awon idajo esin ti o so mo o.
 
Idanileko yi so nipa awon eko ti Islam gbe kale fun eniti o ba ngba aawe gege bii yiyara fun isinu ati lilora lati je saari, bakannaa ni oludanileko tun so oro nipa asiko ti aawe maa nbere ati asiko ti o maa npari, o si tun so nipa bi esin Islam se se aawe agbayipo ni eewo.
 
Idanileko yi so alaye gbogbo awon idajo ti o ro mo gbigba iwaju eni ti o ba n ki irun koja, yala eni ti o fi nkan si iwaju re tabi eni ti ko fi nkankan si iwaju.
 
Idanileko yi je alaye lori hadiisi eleekeje ninu tira “Umdatul Ahkaam”, koko oro idanileko naa ni alaye nipa bi ojise Olohun- ike ati ola Olohun ki o o maa ba a- se maa nse aluwala.
 
Alaye die ninu awon Aayah ibere Suratu Bakora pelu alaye ekunrere lori itumo “Idaayah” ati awon nkan miran.
 
Diẹ ninu awọn okunfa ipanle, janduku ati aigbọran ti awọn ọmọ ya kalẹ si awujọ.Itẹsiwaju ninu alaye awọn okunfa ipanle pẹlu awọn ọna abayọ si awọn iwa buburu yii.
 
Y
Yiyo Saka
Daily+
 
Oro nipa awon ohun ti a maa nyo Saka ninu won, ati oundiwon ti a o yo ninu awon nkan ti Saka wo, Olubanisoro si bere pelu Aayah Alukuraani ti o nso nipa ijiya ti nbe fun awon ti won maa nko dukia jo laiyo Saka ninu re.
 
Waasi yi se alaye ni ekunrere oro nipa idajo eni ti o ba pa eniyan ninu esin Islam, yala o moomo pa eniyan ni tabi o seesi.
 
Alaye nipa ipo Saka yiyọ ninu ẹsin Islam ati awọn anfaani ti o wa nibi yiyọ rẹ yala ni abala ẹsin ni tabi abala iwa.
 
1- Idanilẹkọ ni agbegbe yii sọ awọn ayọka Alukuraani ati ẹgbawa hadisi ti nse apejuwe bi Ina se ri.2- Alaye awọn okunfa ti o maa nmu eniyan wọ Ina, awọn okunfa yii pin si meji: (1) Okunfa ti o maa nmu eniyan bẹ ninu Ina lọ gbere, (2) okunfa ti o maa nmu Musulumi bẹ ninu Ina fun igba diẹ.
 
Alaye ni ẹkunrẹrẹ waye ninu idanilẹkọ yii lori ẹkọ ti o rọ mọ gbogbo ẹni ti n se isẹ sin eniyan.
 
Idanileko yi so nipa awon nkan wonyi:(1) Itumo Ayanmo. (2) Gbigba ayanmo ni ododo je okan ninu awon origun igbagbo. (3) Olohun ti O da awa eda ni O da awon ohun ti a n se ni ise. (4) Awon ipele Ayanmo. (5) Ninu awon idi ti Olohun fi se Ayanmo ni ohun asiri ati ipamo.
 
1- Eleyi ni oro nipa ohun ti o je ojuse Musulumi nibi ibo didi ati idajo Islam lori kikopa ninu idibo.2- Itesiwaju nipa ohun ti Islam so lori eto oselu tiwa- ntiwa (Demokiresi), olubanisoro menu ba idajo esin lori dida egbe oselu sile ati kikopa ninu re, o si tun so nipa ojuse eniti o ba fe gbegba fun ipo oselu.
 
Waasi yi so nipa idajo Islam lori orin kiko ati gbigbo. Oniwaasi mu awon eri ti o po wa lati inu Al-kurani ati hadiisi lori bi orin gbigbo ati kiko se je eewo ninu Islam. Bakannaa ni oro waye ninu waasi yi lori awon aburu repete ti o wa nibi gbigbo orin ati kiko.
 
Awon janmoo Islam ti o wa ni awujo ni anfaani pupo, awon ni won nse itoju awon omo Musulumi ti won ko je ki opolopo won ti sina tabi di keferi, won maa nse alaye esin fun awon omode ati odo ati agbalagba, bibe won ni awujo si je amin isokan fun awa Musulumi. Sugbon apa kan ninu awon janmoo yi ni awon aleebu kookan gege bii ki a gba wipe olori janmoo ko le se asise ati wipe janmoo ti a ba wa ninu re nikan ni ona sunna ti o dara julo, irufe awon nkan yii ni olubanisoro menu ba ninu waasi yi.
 
1- Ninu idanilẹkọ yii ọrọ waye nipa awọn ojuse ti Islam fẹ fun ẹni ti ko ni alaafia lati se ati awọn ojuse ti Ẹsin fẹ fun awọn olutọju rẹ ki wọn se fun un.2- Itẹsiwaju ninu alaye awọn ojuse ti Islam fẹ fun awọn olutọju alaare lati se nigbati o ba npọkaka iku.3- Ni abala yii, alaye ti o kun waye nipa awọn ojuse ti Islam fẹ ki a se nigba ti oku ba ku tan.
 
1- Ibanisoro yii da lori awon ona abayo si asigbo esin ti o gbaye kan laarin awon Musulumi.2- Ibanisoro je afikun lori awon okunfa ati ona abayo si awon asigbo tabi aseju ninu esin.
 
Loading …
show series
 
In one fell swoop, delightful RPCV Ninu Sidhu breaks the internet-based radio show's longstanding glass ceiling and completely transmogrifies the host's perception of Liberia: a land of great hospitality, of reasonable stability, and perhaps even of some measure of hope. This episode is a slow burner. Put on a cup of coffee. Drop some acid. Go ...…
 
Title: Won ti s’awon kan d’akaso ninu Ijo Description: Once again, this episode expose the abuse of money in the church and it is also a comprehensive explanation of how and how not to spend money in the Church.
 
Looking Glass - "Jimmy Loves Mary-Anne" Skeeter Davis - "Let Me Get Close to You" Gene O'Quinn - "Joe Joe Joe" Tempests, The - "You Don't Know Like I Know" Louis Prima - "Scuba Diver" Devin Hill - "Stars" Beach Boys, The - "How She Boogalooed It (2017 Remix)" Ray Mason - "Sometimes In Love" Little Esther Phillips - "Mo Jo Hannah" Ben Vaughn Qui ...…
 
Looking Glass - "Jimmy Loves Mary-Anne" Skeeter Davis - "Let Me Get Close to You" Gene O'Quinn - "Joe Joe Joe" Tempests, The - "You Don't Know Like I Know" Louis Prima - "Scuba Diver" Devin Hill - "Stars" Beach Boys, The - "How She Boogalooed It (2017 Remix)" Ray Mason - "Sometimes In Love" Little Esther Phillips - "Mo Jo Hannah" Ben Vaughn Qui ...…
 
1. Heeby-Jeebies - Little Richard2. Rockbilly Boogie - Johnny Burnette3. Buzz Buzz Buzz - The Hollywood Flames4. The Hucklebuck - Chubby Checker5. Such A Night - Elvis Presley SET 26. The Majestic - Dion7. Leave My Woman Alone - Ray Charles8. KC Loving - Little Willie Littlefield9. There Goes My Baby - The Drifters SET 310. Too Many Fish In The ...…
 
Ìkan nínú àwòn ìtàn abaun – One of the Tortoise Stories (Yoruba)Told by Kunle Adesua at Treasure Language Storytelling, Melbourne Trades Hall, in celebration of International Mother Language Day, February 2017.http://treasurelanguage.org/melbourne-february-2017.html
 
YOFUKASHI RADIO EPS 040: Kuroi Kokoro Play in new window | Download Tracklist: 1. Injection of Blackness – Malika B and Dave Hucker 2. Kalimbas – Hector Plimmer 3. Bruxo – Nicola Cruz 4. Indian Spice – Amin Payne 5. Bangalore Whispers (Andi Otto Remix) – Andi Otto 6. She Said – Sango 7. Mantis – Nicola Cruz 8. Ninu Opon Ori Tiwa (Kiko Navarro R ...…
 
1. Corinda & AfroTura – Aso 2. Amberoom – Rhit 3. Luka Feat. Sio Blackwidow – Yum Yum (N’Dinga Gaba Diplomacy Soul Remix) 4. Sir LSG Feat. Ayanda Jiya – Sandcaste (Sir LSG Main Mix) 5. Dj Jacko Feat. Chelsea Como – Paradise (Blackkdraft Mix) 6. Black Motion Feat. Miss P – It’s You 7. Moon Rocket – Beautiful (The Moon Mix) 8. Mabiisi – King (Sobek ……
 
2hrs of Soulful treats for ya listening pleasure, pure vibes from start to finish.1.Heather Johnson - Happiness (Reelsoul & Larry E Remix)2. Luca Lala, Tiziano Di Sansa - Sax Pleasure (Souldynamic Remix)3. Sandy Rivera, Haze - Changes (K.O.T Vinyl Showcase)4. Wipe the Needle ft Kenny Bobien - Where I Live (Guyana Son Remix)5. Stephanie Cooke - ...…
 
MODERN SOUL RADIO::EP 259Part 1 mixed by DAVID MONTOYA (Tribe Records, United Tribes,LA)1.Afroschnitzel - Generation Why2.Pietro Nicosia - Africanbeatz (MoBlack Dub)3.Adam Port ft Stereo MC’s - Changes (Adam Port Remix)4.Marie Joly & Black Coffee - Gratitude (Pablo Fierro Remix)5.Mr. Joe - Vector Groove6.Stones & Bones ft Toshi - Amahloni (Mano ...…
 
Ännu en gång är det dags, det vill säga återigen hög tid, för Knappt Debatt! Vi uppskattar att ni lyssnar (om ni nu orkar med det) och vill poängtera att veckans avsnitt avhandlar följande ämnen: Kommer vinyltrenden hålla i sig? Har Håkan Hellström sin bästa tid framför sig? Och finns spöken?By knapptdebatt@gmail.com (Knappt Media(?)).
 
Avvikelser och lyten. Visst. Men det finns en frihet i marginalen, menar Aase Berg, som i dikten och musiken ser avvikelser som kan kasta normsystemet överända. Vi borde sluta titta. Det är skillnad mellan hur saker känns när man tittar och när man blundar. Till exempel när det gäller sex.Visst, sex kan förstås ha en hel del med synen att göra. ...…
 
Den här veckan lever vi upp till vår tagline, en podcast om ingenting, då en av våra mikrofoner krånglade så mycket att vi valde att skrota hela avsnittet. Därför får ni nu WeSpawn's hittills kortaste avsnitt med enbart quiz-delen. Vi är väldigt ledsna för detta, men ser nu fram emot ett nytt fantastiskt avsnitt nästa vecka istället. Kram på er ...…
 
Annas och Torbjörns son gjorde av med familjens semesterkassa när han spelade Minecraft på nätet. Kaliber synar idag handeln som riktar sig till barn i ett av världens största dataspel. Världens största dataspel Det här är ju första gången vi gör det här, att vi loggar in på Minecraft-servern. Ni har provat Minecraft lite innan? frågar läraren ...…
 
Ojojoj. Tänk att ni nu ska få lyssna på ett avsnitt som det verkar som om världen inte ville skulle bli av. Jag kommer förklara det här i podden också, men jag tänkte ta det en gång till för säkerhets skull. På grund av strul med ljudet blev nästan hela avsnittet inspelat med fel mikrofon, […]
 
Playlist: - voicebreak - - voicebreak - - voicebreak - Mulatu Astatke- Yegelle Tezeta - New YorkAddisLondon Story Of Ethio Jazz 6575 Nene Tchakou- Cissey - Cesser Le Feu CHATA ADDY AND SUSUMA- This Is What I Feel - THIS IS WHAT I FEEL Mecca Bodega- Ravine - Skin Sola Akingbola- Ninu Opon Ori Tiwa - Routes To Roots Amadou Kienou- Kana Kassi - Ry ...…
 
Äntligen är semestern över och man kan gå tillbaka till det man verkligen älskar, att sitta inomhus och se på film. Nu behöver vi inte längre äta glass i solen, bad i någon halvtaskig sjö och svettas på en trång buss. Äntligen är vi tillbaka. Inte nog med att allt är precis som vanligt, vi har en ny kvist och någon ny typ a jingle för den också ...…
 
COSMOS FINALE! Ja ni, nu är serien slut och så även podcasten. Vi diskuterar serien i stort, förklarar fusionskraft och dissar Solar Freakin’ Roadways. Missa ej! Inlägget #Special: Superlife Cosmos 12/13 dök först upp på Superlife Podcast.By Superlife Podcast.
 
Google login Twitter login Classic login